Ojú òpó ajàfẹ́tọ̀ọ́ ẹni: Àádọ́ta lọ́yà ló wà ń bẹ̀ láti jà fún ọ
Ǹ jẹ́ o mọ ẹ̀tọ́ rẹ lábẹ́ òfin?
Tóò bá mọ̀ọ́, ayé ti dáa dé báyìí láti mọ gbogbo ẹ̀tọ́ tóo ní ní èdè abínibí wa ní Nàíjíríà.
Iléesẹ́ asojú Amẹ́ríkà ní Nàíjíríà sèfilọ́lẹ̀ ojú òpó tí yóò sọ gbogbo ẹ̀tọ́ tóo ní fún ọ̀ lóríí fóónù àti kọ̀ńpútà rẹ.
Bákan náà lo tún leè gba agbẹjọ́rò bíi ààdọ́ta lórí ojú òpó yìí láti jà fún ọ.