Fídíò àkàndá ẹ̀dá tó di amòfin

Àkọlé fídíò, Fídíò àkàndá ẹ̀dá tó di amòfin

Patcharamon Sawana jẹ́ ọmọ orílẹ̀èdè Thailand.

Ẹ́ni ọdún mẹ́tàlélógún ni Patcharamon Sawana bẹ̀rẹ̀ iléẹ̀kọ́ lẹ́yìn tí òfin fààyè gba àwọn àkàndá láti lọ sílé ìwé.

Ó ti kọ́kọ́ sisẹ́ olùkọ́, kó tó lọ fún isẹ́ amòfin.

Àwọn iròyin tì ẹ leè ní ìfẹ̀ síí: