Ilẹ̀ gbígbẹ́ ní Bọ́ùn: Ìpìnlẹ̀ mẹ́fà leè má nìí iná ọba

Àkọlé fídíò, Ilẹ̀ gbígbẹ́ ní Bọ́ùn: Ìpìnlẹ̀ mẹ́fà leè má nìí iná ọba

Ìwádìí BBC Yorùbá ní agbègbè Bọ́ùn ní ìpínlẹ̀ Ògùn fihàn pé, ó seése kí ìpìnlẹ̀ mẹ́fà lẹ́kùn ìwọ̀ òòrùn gúúsù Nàíjíríà má nìí iná ọba nítori àwọn ọlọ́kọ̀ akóyọyọ tó ń wa yèèpẹ̀ níbẹ̀, ti wa yèèpẹ̀ wọn dé abẹ́ wáyà iná alágbára tó ń gbé iná ọba wá sáwọn ìpínlẹ̀ náà.

A gbọ́ pé táwọn wáyà iná alágbára náà bá fi wó, yàtọ̀ sí pé ó leè gbẹ̀mí èèyàn, ó tún leè mú kí iná ọba lọ fún ọ̀pọ̀lọpọ̀ ọjọ́ lẹ́kùn ìwọ̀ òòrùn gúúsù Nàíjíríà.

Àwọn iròyin tì ẹ leè ní ìfẹ̀ síí: