Ọlọ́pàá Kwara: À ń wá àwọn adigunjalè tó pa èèyàn méjìlá

Àkọlé fídíò, Òkú sùn nínú ìṣẹ̀lẹ̀ ìdigunjalè ní Ọ̀ffà

Àwọn adigunjalè náà pa ọlọ́pàá mẹ́fà àti àwọn ará ìlú mẹ́fà níbi ìkọlù sí àwọn ilé ìfowópamọ́ márùń ní ìlú Ọ̀ffà.

Àwọn iròyin tì ẹ leè ní ìfẹ̀ síí: