Ayẹyẹ ifilọlẹ ileeṣẹ BBC Yoruba nipinlẹ Eko

Ifilọlẹ BBC Yoruba, Igbo ati Pidgin ni ẹkun iwọ oorun Africa waye nipinlẹ Eko.

Ileeṣẹ BBC ṣe ifilọlẹ BBC Yoruba, Igbo ati Pidgin ni ipinlẹ Eko
Àkọlé àwòrán, Ileeṣẹ BBC ṣe ifilọlẹ BBC Yoruba, Igbo ati Pidgin ni ipinlẹ Eko
Ogunlọgọ awọn ara ati ọrẹ peju-pesẹ sibi ifilọlẹ naa to waye ni Ikoyi lọjọru
Àkọlé àwòrán, Ogunlọgọ awọn ara ati ọrẹ peju-pesẹ sibi ifilọlẹ naa to waye ni Ikoyi lọjọru
Agbẹnusọ fun Aarẹ Muhammadu Buhari, Ọgbẹni Garba Shehu
Àkọlé àwòrán, Agbẹnusọ fun Aarẹ Muhammadu Buhari, Ọgbẹni Garba Shehu darapọ mọ awọn ololufẹ BBC
Oga agba ileeṣẹ amohunmaworan Channels, John Momoh naa pẹlu nibi ayẹyẹ yi
Àkọlé àwòrán, Oga agba ileeṣẹ amohunmaworan Channels, John Momoh naa pẹlu nibi ayẹyẹ yi
Taiwo Kola-Ogunlade ati Dorothy, awọn oṣiṣẹ Google naa wa sibẹ

Oríṣun àwòrán, Taiwo Kola-Ogunlade

Àkọlé àwòrán, Taiwo Kola-Ogunlade ati Dorothy, awọn oṣiṣẹ Google naa wa sibẹ
Oluwo ti ilu Iwo, Oba Abdulrasheed Adewale Akanbi pẹlu olori rẹ
Àkọlé àwòrán, Oluwo ti ilu Iwo, Oba Abdulrasheed Adewale Akanbi pẹlu olori rẹ
Awọn oṣere tun ṣe bẹbẹ nibi ayẹyẹ yii pẹlu oriṣiriṣi ara dida
Àkọlé àwòrán, Awọn oṣere tun ṣe bẹbẹ nibi ayẹyẹ yii pẹlu oriṣiriṣi ara dida
Yoruba ree. Ilu ree. Ijo ree. Orin ree. Ayẹyẹ ya
Àkọlé àwòrán, Yoruba ree. Ilu ree. Ijo ree. Orin ree. Ayẹyẹ ya
Awọn ijoye ati agbaagba ilu nile Ibo naa joko pẹlu ṣe ayẹyẹ yii
Àkọlé àwòrán, Awọn ijoye ati agbaagba ilu nile Ibo naa joko pẹlu ṣe ayẹyẹ yii