L'Eko awọn eeyan fero wọn han lori ile-isẹ kolekodọti tuntun

Àkọlé fídíò, ‘Ile-ise kolẹkodọti ko sisẹ to l’Eko’

Ọpọlọpọ eniyan sọwipe ile isẹ akodọti tuntun t'ilu Eko ko kun'juwọn nitori idọti si wa lawọn agbeegbe to pọ.