You’re viewing a text-only version of this website that uses less data. View the main version of the website including all images and videos.
Bọlanle Okusanya Feyita: Mo máa ń sùn sínú pósí ní kékeré
Ọmọbinrin asaraloge to wa di asayẹyẹ f'oku leyin ti baba ati aburo rẹ ku ninu ijamba ọkọ ofurufu nigbati awọn naa fẹ lọ sayẹyẹ f'oku.