You’re viewing a text-only version of this website that uses less data. View the main version of the website including all images and videos.
Ọbẹ egusi dun gaani
Ọbẹ egusi dun gaani, o ni orisirisi eroja awọn Yoruba si gbadun lati maa jẹ. Awọn ọmọ Naijiria to wa ni ilu Gẹẹsi so nipa adun obẹ naa.