Afẹ Babalọla: Iyan ni mo fẹran julọ ninu ounjẹ
Ilumọọka agbẹjọro kan lorilẹede Naijiria, Oloye Afẹ Babalọla ti sọ faraye pe iyan ni oun kundun julọ ninu ounjẹ ilẹ Kaarọ oojire.
Babalọla ni ki oun to lọ se ẹjọ ni aarọ, oun yoo jẹ iyan, bakaanaa ni lọsan ati ni alẹ.