Ibikunle Amosun: Owo adani ni'ṣẹ ẹran dida, ko kan ijọba

Àkọlé fídíò, Ibikunle Amosun: Owo adani ni'ṣẹ ẹran dida, ko kan ijọba

Gomina ipinlẹ Ogun, Ibikunle Amosun ti woye pe ko si ohunkohun to kan ijọba lẹlẹkajẹka ninu iṣẹ ẹran dida.

O ni niwọn igba to jẹ pe awọn eeyan to nra ẹran wọnyi maa nsanwo fun ẹni to n ta ni, eyi ti foju han pe owo adani ni iṣẹ ẹran sinsin.