'Nnamdi Kanu gbọdọ foju han ki Igbo to d'ibo ni 2019'

Àkọlé fídíò, Idibo ko ni waye ti wọn ko ba mu ọkọ mi jade

Ile isẹ BBC ni ifọrọwanilẹnuwo pelu iyawo olori ẹgbẹ Ipob, Nnamdi Kanu, arabinrin Uchechi Kanu.

O salaye pe ti ijọba orilẹede Naijiria ko ba wa ọkọ oun jade nibi to ba wa, ẹya Igbo ko ni dibo ni ọdun 2019.

Awọn iroyin ti ẹ lee nifẹẹ si: