Cow Dung: Ẹ̀ Wo ohun tí wọ́n n fí ìgbẹ́ màlúu ṣe ní ilú yìí

Àkọlé fídíò, Cow Dung: Ẹ̀ Wo ohun tí wọ́n n fí ìgbẹ́ màlúu ṣe ní ilú yìí

Ọdọọdun ni wọn ma n ṣajọyọ ọdun Gorehabba ni abule Gummatapura lorilẹede India pẹlu igbẹ maluu.

Awọn olugbe agbegbe naa gbagbọ pe inu igbẹ maalu ni wọn bi orisa wọn, Beereshwara Swamy si.

Ẹkunrẹrẹ fidio naa ṣafihan bi wọn ṣe n fi igbẹ maluu dara ni orilẹede India nitori igbagbọ wọn nipa rẹ.