Osun 2022 election: Wo ibi ti ọ̀rọ̀ dé dúrò báyìí nípinlẹ̀ Osun

BBC ba àwọn eeyan ipinlẹ̀ Osun sọrọ lori ohun to n ṣẹlẹ bayii saaju idibo apele ẹgbe oṣelu All Progressives Party.

Awọn eekan ẹgbẹ APc ni igun loriṣiirisii ni anfani lati ba BBC sọrọ.Ìbẹ̀rù-bojo gbalẹ̀ ṣáájú ìdìbò abẹ́nú gómìnà ẹgbẹ́ APC ní ìpínlẹ̀ Osun lọ́la

Bi awọn kan ṣe n ni pe ọrọ oṣelu ko ye Oyetola bẹẹ naa ni awọn mii ni pe Aregbesola ni lọwọ ti ẹlomii ni pe Bola Tinubu naa ni tiẹ lara.