Oloye Peter Fatomilola: Ọjọ̀gbọ́n olùkọ́ni ni Jesu àti Orunmila jẹ́, àwòkọ́ṣe sí rere si ni wọ́n

Wo bi Orunmila àti 'Mechizedek' inu Bíbélì ṣe tan mọ ara wọn- Peter Fatomilola

Oloye Peter Fatomilola salaye ni kikun fun BBC Yoruba ajọṣepọ to wa laarin Jesu Kristi inu bibeli mimọ ati Orunmila.

Ọjọ̀gbọ́n olùkọ́ni ni Jesu àti Orunmila jẹ́, àwòkọ́ṣe sí rere si ni wọ́n.

Baba Peter Fatomilola sọrọ nipa iwa omoluwabi ninu iran yoruba.

O gba awọn eeyan nimọran lati ni iwa omoluwabi lẹnu iṣẹ, ninu ile ati laarin ẹbi.

Bakan naa lo gba imọran pe ki awọn akẹkọọ maa kọ nipa Ifa nile ẹkọ.

Njẹ́ ìwọ ń ṣe ìfẹ́ Olodumare lẹ́nu iṣẹ́ rẹ bí?

Ta ni Yorùbá ń pè ní Omoluwabi?