You’re viewing a text-only version of this website that uses less data. View the main version of the website including all images and videos.
Ose Aboke Ancient soap: Wo ọṣẹ ìṣẹ̀ǹbáyé tí ìran Yorùba fi gbéná wojú àwọn Fulani láyé àti
Oṣẹ Aboke jẹ ọṣẹ iṣẹmbaye ti awọn ara ilu Aboke ṣi n wari fun titi di oni fun ipa pataki to n ko ninu ilera awọn eniyan.
Oloye Fasola Famapowa to jẹ Oloye Aboke ti ilu Ibadan ati olori ẹbi awọn Aboke to n gun ọṣẹ naa ni arun bii igbona atawọn mii to fara pẹ ẹ ni ọṣẹ yii le wosan.
Ara ile Aboke gbe itan kalẹ fun BBC Yoruba pe lasiko ogun to bẹ silẹ laarin awọn ẹya Tapa ati Yoruba nigba naa lọhun.
Oloye Fasola ni Ogun awọn Ebira lawọn kọkọ koju nilu awọn ki ti Fulani to bẹrẹ. O ni "nigba ti ilẹ yoo fi mọ awọn Igbira, wọn o mọ ohun ti wọn ṣe mọ".
Wọn da igbona si awọn ẹya Yoruba lara amọ ọṣẹ naa lo jẹ angẹli ti Eledua ran si wọn.
- Àwọn tó ní "passport" orílẹ̀èdè mìí, Igboho àti Kanu ló fẹ́ da Nàìjíríà rú, ẹ má tẹ̀lé wọn o! - Kemi Olunloyo
- 'Nàiìjíríà ti pèsè ''Private jet'' tí yóò gbé Igboho padà sílé láti Cotonou sílẹ̀ kí ìgbẹ́jọ́ rẹ̀ tó bẹ̀rẹ̀'
- Gbogbo ẹ̀yin Mùsùlùmí Yorùbá tí ẹ ń pè fún Yorùbá Nation ẹ lọ tún èrò yín pa - Ishaq Akintola
- Wọ́n ti fi ẹ̀sùn míì kan Sunday Igboho ní ìlú Benin! - Agbẹ́jọ́rò Igboho
- Baba Ijesha: Wọ́n gbé ọmọdé kan wá sílé ẹjọ́ kó wá jẹ́rìí sí ẹ̀sùn Baba Ijesha àti Princess
- Ọmọ Ìjọ Deeper Life Pọ́ńbélé ni ìyà mi àti bàbá mi, mo sì dàgbà síbẹ̀ àmọ́ bíbọ Èṣù ọ̀dàrà lọ́nà tó tọ́ -
- Ẹ gbé Sunday Igboho kúrò láhàmọ́ ọlọ́pàá wá sí ibi ìpamọ́ mìí ní Cotonou títí tí... - Adájọ́
- 'Ìjìyà Ọlọ́run n'ìjọba Buhari' - Sẹ́nétọ̀ Okunrounmu
- Pẹ̀lú omijé lójú làwọn òbí akẹ́kọ̀ọ́ 28 Bethel Baptist táwọn ajínigbé tú sílẹ̀ fi pàdé ọmọ wọn
- Àwọn ọ̀nà tí òfin tuntun CBN lórí Bureau De Change tí wọ́n gbé'gi lé ṣe kàn ọ́
- Oríire ńla ni ìdájọ́ El-Zakzaky jẹ́ lẹ́yìn ọdún mẹ́fà ní ọgbà ẹ̀wọ̀n - IMN
Ẹwẹ, pẹlu ohun ti a ri, ọṣẹ naa ṣi wa laye titi di oni to si n ṣe bẹbẹ bii tatijọ.
Idile Aboke ti a kan si ni awn ni lọrun fi ṣiṣe irubọ ati gigun ọṣẹ naa pọ ti wọn yoo tun gbadura si Oke Ibadan to jẹ apata giga kan ni ilu Ibadan.
Wọn ṣi nigbagbọ pe ọṣẹ naa ṣi n wo aruin igbona titi doni koda, wọn lee tun gun ọṣẹ naa pọ mọ awọn nkan mii fun eeyan fun oniruuru ojutuu ni ilana ibilẹ ti wọn ba n wa si iṣoro wọn.