You’re viewing a text-only version of this website that uses less data. View the main version of the website including all images and videos.
Adebayo Shittu: Èmi kò ṣẹ Abiola Ajimobi nígbà ayé ẹ, òun ló ṣẹ̀ mi ṣùgbọ́n.....
Ajimobi maa n ni pe Shittu le pupọ. mo kan kọ irẹjẹ ati iwọsi ni- Adebayo Shittu
Minista ọrọ ibaraẹnisọrọ ni Naijiria tẹlẹ, Amofin Adebayo Shittu gba BBC lalejo nile rẹ.
Ninu ifọrọwanilẹnuwo naa lo ti sọ ohun to ṣẹlẹ laarin rẹ ati oloogbe Abiola Ajimobi to jẹ gomina ipinlẹ Oyo tẹlẹ ati ibi ti ọrọ de duro pẹlu Florence, aya gomina Ajimobi bayii.
- Agbébọn pa ọ̀gá àgbà ọlọ́pàá nígbàkan rí, Christopher Deja
- Ìjọba Buhari ti gbẹ́rù tó kọjá orí, bàtá tó bá ń ró lákọ fẹ́ ya ni!- Tunde Bakare
- Lẹ́kṣọ́rà fásitì FUOYE kan tún kó sí gbaga ẹ̀sùn aṣemáṣe pẹ̀lú akẹ́kọ̀ọ́
- Abiola Ajimọbi ní ti mo bá di gómìnà, òun á ṣẹ̀wọ̀n ni- Adebayo Shittu
- Ọwọ́ ikọ̀ Amọtẹkun ba Mutiu Abdul-Rasheed, afurasí tó ń ta ẹ̀yà ara èèyàn ní Ibadan
Amofin Adebayo Shittu ni nitori pe Ajimobi kọ lati jẹ ki oun rọpo rẹ nipo gomina lo bi ige ati Adubi to pada ṣẹlẹ.
O ni o dun oun pe ko si agbaagba ẹgbẹ APC kankan to ba wọn da si ija naa nitori ipo. agbara ati owo ti gomina ni.
Shittu ni Ilosiwaju ipinle Oyo lo ku to yẹ ko jẹ gbogbo awọn to ku laye to n wa ni ipo oselu ni ipinlẹ Oyo logun lasiko yii.
O ni pe nitori ko sẹni ti ko ni ku lọrọ ọhun.
- Ọwọ́ ikọ̀ Amọtẹkun ba Mutiu Abdul-Rasheed, afurasí tó ń ta ẹ̀yà ara èèyàn ní Ibadan
- Twitter kò dá sí ọ̀rọ̀ IPOB àti Nnamdi Kanu, bó ṣe wù wa la ṣe lè darí Nàìjíríà- Lai Mohammed
- Ẹ̀yin òṣìṣẹ́ ìjọba, dẹndẹ ìyà yóò jẹ orí yín bí Nàìjíríà bá pínyà pẹ́rẹ́, toríi Yoruba Nation! - Oluwo
- Aàrẹ Muhammadu Buhari gba àmì ẹ̀yẹ Adarí tó dára jùlọ
- UNILAG jáwé lọ gbélé ẹ fún àwọn olùkọ̀ méjì tí BBC tú àṣírí wọn nínú fíìmù 'Sex For Grades'
Adebayo Shittu sọ bi oun ati baba Ganiyu Ajimobi to jẹ baba gomina Abiola Ajimobi ṣe jọ wa nile igbimo asofin ni Oyo nigba naa ati bi Baba Ganiyu Ajimbi se mu oun bii ọmọ.
O ni oun ati Ajimobi pada ri ara wọn ko to ku.
O parọwa pe ki agba oloselu mu ilọsiwaju awọn eeyan rẹ lọkunkundun.