Christmas celebrations: Báyìí ni Odunlade Adekọla, Mide Martins, Mercy Aigbe àtàwọn òṣèré fíìmù Yorùbá míràn kí àwọn olólùfẹ́ wọn kú ọdún

Wo àwòrán bí ọdún Keresimesi ṣe ń lọ káàkiri àgbàyé

Bi gbogbo agbaye ṣe n ṣajọyọ ọdun Keresimesi lọdun, ọpọ ijọ lo dahoro nitori ajakalẹ arun Covid-19 to n mi agbaye titi.

Amọ ṣa, ọpọ eeyan lo ṣe ọdun naa ni iwọnba bi agbara wọn ṣe mọ ati bi asye ṣe gba wọn si.

Wo diẹw lara aworan bi ọdun keresimesi ọdun 2020 ṣe lọ kaakiri agbaye.