You’re viewing a text-only version of this website that uses less data. View the main version of the website including all images and videos.
The New Pandemic: Kíni àwọn onímọ̀ sáyẹ́ńsì ń sọ nípa rẹ̀?
Ẹ gbé owó silẹ̀ fún àwọn iṣẹ iwadii lori wọn ki wọn to tun maa gbẹbọ lọwọ agbaye- Awon onimọ sayẹnsi
Sars, Swine Flu, Spanish Flu, MErs, Ebola ati Coronavirus jẹ diẹ lara awọn ajakalé arun to ti mu ẹmi ọpọ eniyan lọ ni gbogob agbaye sẹyin.
Bayii, ọpọlọpọ orilẹ-ede ni ko tii bọ lọwọ iṣoro ajakalẹ arun coronavirus titi di asiko yii.
Sugbọn awọn onimó sayẹnsi ni agbaye tun ti n pariwo ajakalẹ arun miran ti wọn ni o m bọ lọna ti o ṣeeṣe ko di nla ni agbaye.
- Nígbà tí mo dàgbà ní mo rí i pé oore ńlá ní Olorun ṣe mi pẹ̀lú aàbọ̀ ara mi- Bose Okeowo
- Èèyàn méjì àti ọkọ̀ 29 ló jóná níbi ìṣẹ̀lẹ̀ táńkà agbépo tó gbiná ní mọ́rosẹ̀ Eko sí Ibadan
- Ẹ gbà mí o! Ìjọba Buhari ní kí Ológun pa mí láàrin ọjọ́ kan péré - Omoyele Sowore
- 'Cartoon' nípa Anọbi Muhammed kó Ọ̀jọ̀gbọ́n kan sí ìyọnu ní Egypt
Orilẹ-ede China ni wọn tun ti ni yoo ti fẹẹ jade.
Wọn ni ajakalé arun naa ko tii lewu lasiko yii ṣugbọn ẹfọn, ayipada oju ọjọ ati ooru lee sọo di nla mọ agbaye lọwọ.
Awọn onimọ sayẹnsi parọwa pe ki awọn eeyan gbe owo silẹ fun iṣẹ iwadii ki ajakalẹ arun naa to di nkan miran ni agbaye,
- Àwọn Olùkọ́ ìpínlẹ̀ Eko dárà lórí Akọ́mọlédè àti Àṣà lórí BBC
- Shomolu gbajúmọ̀ fún ìwé títẹ̀ ní gbogbo Nàìjíríà!
- Àwọn ọmọ Nàìjíríà yarí lórí èròngbà ilé aṣòfin pé kí àjọ FRSC má a lo nkan ìjagun
- Àwọn ìwàásù akọnilẹ́nu hàà tí Prophet Israel Oladele CCC Genesis Global ti ṣe rèé
- Kí lo mọ̀ nípa ìgbeyàwó Àbẹ̀ẹ́lẹ̀, Àṣàǹte, Ọkọ Káalẹ́ àti Gbàmí o ràmí?