Coronavirus: Wo bí àwọn ará Ibadan ṣe n ṣe lásìkò Coronavirus yìí

Bi àwọn kan ṣe n ní òye síi lórí ààbò lásìkò arun Coronavirus yii ni àwọn míràn kò bìkítà tó!.

corona
Àkọlé àwòrán, Ẹ gba mi! Eeyan meloo lori ọkada yii ni Ibadan lasiko Coronavirus to yẹ ki gbogob wa maa ṣọra yii
corona
Àkọlé àwòrán, Baba Elẹran àti awon onibara wọn ni wọn duro gbágbá lẹ́gbẹ ara wọn lọja ni Ibadan
corona
Àkọlé àwòrán, Awọn ọlọkada ati marwa lo n ko ero bi adaba ti ko naani a n kun igbẹ yii!
corona
Àkọlé àwòrán, Awọn ọlọkada lo kunlẹ gbagba yii ti wọn ṣetan lati gbe awọn ero
corona
Àkọlé àwòrán, Awọn onimọto naa n ko ero wọn bi wọn ṣe fẹ nigboro Ibadan bayii
corona
Àkọlé àwòrán, Awọn ero ree lọkunrin lobinrin ti wọn n duro ti ara wọn lati gba owo ni banki ifowopamọsi.
corona
Àkọlé àwòrán, Awọn ero lo kun inu kẹkẹ Marwa yii ni opopona ni Ibadan lai bẹru Corona Virus
corona
Àkọlé àwòrán, Tọkunrin tobinrin lo n wọnu ọja lati ra nkan sile nitori bi igboro ṣe ri lori ọrọ Corona virus
corona
Àkọlé àwòrán, Ẹ wo awọn eeyan ti wọn n wo fuu pe wọn ko mọ ohun to ku
corona
Àkọlé àwòrán, Oṣiṣẹ ile ifowopamọ kan ree to n fun awọn onibara ni ohun eelo wiwẹ ọwọ ṣaaju ki wọn to wọ ile ifowopamọ
corona
Àkọlé àwòrán, Awọn oṣiṣẹ ọlọkọ ero ni Ibadan ree ti wọn duro gbagba ti ara wọn lopopona.
corona
Àkọlé àwòrán, Awọn ero miran ree ti wọn fun ara wọn ni aaye laarin ara wọn ki wọn to wọnu banki