Emir of Kano: Àwọn àwòrán Sanusi nígbà tó ṣì wà lórí oyè bíi Emir

Àwọn àwòrán mọ́kànlá Lamido Sanusi lẹ́nu iṣẹ́ kí wọ́n tó yẹ àga mọ nídì.

Sanusi

Oríṣun àwòrán, DESIGNED BY STUDIO

Àkọlé àwòrán, Sanusi, Emir kẹrinla ilu Kano nibi ayẹyẹ kan
Sanusi

Oríṣun àwòrán, INSTAGRAM / KANO KINGDOM

Àkọlé àwòrán, Emir ana, Sanusi ati aarẹ ilẹ Ghana, Nana Akufo Addo
Sanusi

Oríṣun àwòrán, INSTAGRAM / KANO KINGDOM

Àkọlé àwòrán, Muhammadu Sanusi keji pẹlu Sultan Muhammad Sa'ad Abubakar nibi aṣeyẹ kan.
Sanusi

Oríṣun àwòrán, INSTAGRAM / KANO KINGDOM

Àkọlé àwòrán, Sanusi joye Emir lẹyin baba to bi baba rẹ, Sanusi kinni, ti wọn rọ loye bakan naa.
Sanusi

Oríṣun àwòrán, INSTAGRAM / KANO KINGDOM

Àkọlé àwòrán, Emir ana, Sanusi pẹlu Aarẹ Muhammadu Buhari.
Sanusi

Oríṣun àwòrán, EMIHD KANO EMIRATE

Àkọlé àwòrán, Sanusi wa lori alefa gẹgẹ bi Emir fun nkan bi ọdun mẹfa.
Sanusi

Oríṣun àwòrán, INSTAGRAM / KANO KINGDOM

Àkọlé àwòrán, Emir ana, Sanusi ati ọgbẹni Nitin, lati Skline Unirversity, Kano.
Sanusi

Oríṣun àwòrán, INSTAGRAM / KANO EMPIRE

Àkọlé àwòrán, Sanusi pẹlu awọn eeyan.
Sanusi

Oríṣun àwòrán, INSTAGRAM / KANO KINGDOM

Àkọlé àwòrán, Sanusi ati onimọ nipa ẹsin Musulumi, Mufti Ismael Menk
Sanusi

Oríṣun àwòrán, INSTAGRAM / KANO KINGDOM

Àkọlé àwòrán, Sanusi nigab to ṣi wa lori apere
Sanusi

Oríṣun àwòrán, INSTAGRAM / KANO KINGDOM

Àkọlé àwòrán, Sanusi nibi ayẹyẹ kan ki ijọba kano to rọ ọ loye