Hijab Day: Orin tàkasúfèé ló wù mí kí n máa kọ ṣùgbọ́n Hijab kò jẹ́

Àkọlé fídíò, Mina la voilée, olorin to tun jẹ ajafẹtọ obinri

Mina Voilée ni ohun ti oun nṣe ko ye gbogbo awọn to n bu oun lori ayeluja.