Climate Change: Kí ló kan ọmọ Nàìjíríà tí wọ́n ń darapọ̀ mọ́ ìwọ́de yìí?

Ìtúmọ̀ èyí ni wí pé ọ̀pọ̀lọ̀pọ̀ fífí ìmọ̀ ẹ̀rọ̀ sáyẹ̀ǹsì tọwọ̀ bọ ojú ọjọ́ tí àwọn aláṣẹ́ tọ́rọ̀ kàn ń ṣe ń ṣàkóbá fún aráàlú ní wọ́n ṣe ń wọ́de.

Iwọde lodi si ayipada oju ọjọ ni Naijiria
Àkọlé àwòrán, Iwọde lodi si ayipada oju ọjọ ni ilu Eko, Naijiria
London
Àkọlé àwòrán, Ọmọde kan ree nilẹẹlẹ toun naa ko pali jọ ṣe iwọde lodi si ayipada oju ọjọ
Iwọde lodi si ayipada oju ọjọ ni Naijiria
Àkọlé àwòrán, Iwọde lodi si ayipada oju ọjọ ni Abuja, Naijiria
Senegal
Àkọlé àwòrán, Orilẹede Senegal naa darapọ mọ iwọde lodi si ayipada oju ọjọ lagbaye
London
Àkọlé àwòrán, Ilu London darapọ mọ iwọde lodi si ayipada oju ọjọ lagbaye
Iwọde lodi si ayipada oju ọjọ ni Naijiria
Àkọlé àwòrán, Iwọde lodi si ayipada oju ọjọ ni ilu Eko, Naijiria
Berlin
Àkọlé àwòrán, Awọn aṣewọde ni lodi si ayipada oju ọjọ Berlin
Iwọde lodi si ayipada oju ọjọ ni Naijiria
Àkọlé àwòrán, Iwọde lodi si ayipada oju ọjọ ni ilu Abuja, Naijiria
Kenya
Àkọlé àwòrán, Ike ni awọn aṣewọde ni Kenya orilẹede Nairobi ko sori sọrun lati fi sọpe rara si ayipada oju ọjọ eyi tumọ si siṣe atunlo aloku ike rọba fi pese agbara fun iwulo araalu dipo ki a kan maa ju u nu kiri.
Iwọde lodi si ayipada oju ọjọ
Àkọlé àwòrán, Iwọde lodi si ayipada oju ọjọ ni ilu Eko, Naijiria
Delhi
Àkọlé àwòrán, Ọpọlọpọ ọmọ ile lo wọpọ nibi iwọde ni Delhi lodi si ayipada oju ọjọ
Iwọde lodi si ayipada oju ọjọ ni Naijiria
Àkọlé àwòrán, Iwọde lodi si ayipada oju ọjọ ni ilu Eko, Naijiria