Ijegun Fire: Ẹ̀gbà ọrùn ni wọ́n fi dá òkú ẹnìkan mọ̀ níbi ìṣẹ̀lẹ̀ iná Ijegun

Iròyin tó tẹ̀ wá lọ́wọ́ ni wípé àwọn kan ni wón lọ ji epo ninu ọpa epo rọbi to wa ni Ijegun ni Ipinlẹ Eko.

Ṣugbọn nigba ti ina sọ, awọn ara ilu lo fara kaasa ọrọ naa.

Fidio yii lo ṣafihan bi ibi ina naa ṣe ri nigba ti awọn oṣiṣẹ to n koju iṣẹlẹ pajawiri de ibẹ.

Àwọn ìròyìn mìíràn tí ẹ lè nífẹ̀ẹ́ sí: