You’re viewing a text-only version of this website that uses less data. View the main version of the website including all images and videos.
Zainab Aliyu: Mo sọkún títí, ojé tán lójú mi ní àhámọ Saudi
Oṣu mẹ́rin ni Zainab Aliyu lo ni ahamọ ni orilẹede Saudi Arabia to n reti iku lẹyin ti wọn fẹsun kan pe o gbe oogun oloro wọ orilẹede naa.
Ijọba orilẹede Naijiria ṣe iwadi to fi han wipe awọn janduku oṣiṣẹ papakọ ofurufu to wa ni Kano lo gbin oogun oloro naa sinu apo rẹ. Ijọba Naijiria si fi eyi to ijọba Saudi leti ti wọn fi da ọmọ obinrin naa silẹ.
Ninu fidio yii, oo ṣalaye fun BBC oun toju oun ri ni ahamọ.