African Drum Festival 2019: Ẹ wo àwòrán tó làmìlaaka níbi Àjọ̀dún Ìlù Ọdún 2019!

Ajọdun ilu nilẹ Afrika ti ẹlẹ́ẹ̀kẹrin waye ni ipinlẹ Ogun lorilẹede Naijria jẹ afihan ati ṣiṣe ajọyọ ipa ti ilu n ko nilẹ Afrika.

African Drum Festival 2019

Oríṣun àwòrán, Ogun State Governor's office

Àkọlé àwòrán, Ati ọmọde ati agba lo fẹran ilu lilu nilẹ Afirika nitori wọn fẹran orin lọpọlọpọ
African Drum Festival 2019

Oríṣun àwòrán, Ogun State Governor's office

Àkọlé àwòrán, Ajọdun ilu nilẹ Afrika to maa n waye ni ipinlẹ Ogun l'orilẹede Naijria jẹ afihan ati ṣiṣe ajọyọ ipa ti ilu n ko nilẹ Afrika.
African Drum Festival 2019

Oríṣun àwòrán, Ogun State Governor's office

Àkọlé àwòrán, Ọdọọdun la n rorogbo, ọdun ilu ti ilẹ Afirika ti ọdun yii tun soju ẹmi wa.
African Drum Festival 2019

Oríṣun àwòrán, Ogun State Governor's office

Àkọlé àwòrán, Ọjọgbọn lawujọ, awọn eniyan jankan jankan naa pẹjọ sibi ọdun ilu ti 2019.
African Drum Festival 2019

Oríṣun àwòrán, Ogun State Governor's office

Àkọlé àwòrán, Ni aye atijọ, awọn ìlú nilẹ Yoruba ati kaakiri ilẹ Afrika maa n lo ìlù lati ba ara wọn sọrọ.
African Drum Festival 2019

Oríṣun àwòrán, Ogun State Governor's office

Àkọlé àwòrán, Nibi ọdun ilu ti ọdun 2019 naa ni wọn ti se afihan awọn asa ati awọn aso ibilẹ bii adire ti o wọpọ ni ilẹ Yoruba.
African Drum Festival 2019

Oríṣun àwòrán, Ogun State Governor's office

Àkọlé àwòrán, Ìró ilu maa n jẹ ọna ibaraẹnisọrọ laarin eniyan meji tabi ju bẹẹ lọ, bi ẹrọ ibaraẹnisọrọ ṣe ri l'ode oni.
African Drum Festival 2019

Oríṣun àwòrán, Ogun State Governor's office

Àkọlé àwòrán, Awọn lọbalọba ilẹ Yoruba naa pejo si ibi adun ilu ti ọdun 2019.
African Drum Festival 2019

Oríṣun àwòrán, Ogun State Governor's office

Àkọlé àwòrán, Ni aye atijọ, awọn ọba ìlú nilẹ Yoruba ati kaakiri ilẹ Afrika maa n lo ìlù lati ba awọn ẹmẹẹwa wọn sọrọ.
African Drum Festival 2019

Oríṣun àwòrán, Ogun State Governor's office

Àkọlé àwòrán, Oriṣiriṣi ọrọ aṣiri si ni awọn eniyan maa n lo ilu lati sọ, ẹni to ba si ni eti ilu nikan ni ọrọ naa le ye.
African Drum Festival 2019

Oríṣun àwòrán, Ogun State Governor's office

Àkọlé àwòrán, Ọdun 2016 ni gomina ipinlẹ naa, Ibikunle Amosun fi ajọdun naa le lẹ.
African Drum Festival 2019

Oríṣun àwòrán, Ogun State Governor's office

Àkọlé àwòrán, Ẹlẹẹkẹrin si ni ti ọdun 2019 to n waye nilu Abẹokuta, tii ṣe olu ilu ipinlẹ Ogun.
African Drum Festival 2019

Oríṣun àwòrán, Ogun State Governor's office

Àkọlé àwòrán, Ipinlẹ Ogun lo maa n gbalejo awọn aṣoju ati akopa lati orilẹede bii mẹtalelogun kaakiri ilẹ Afirika.
African Drum Festival 2019

Oríṣun àwòrán, Ogun State Governor's office

Àkọlé àwòrán, Gomina Amosun sọ pe yatọ si ipinlẹ mẹrindinlọgbọn ni Naijiria ti yoo kopa nibi ajọdun naa l'ọdun yii, orilẹede ilẹ Afrika mọkanlelogun, to fi mọ orilẹede UK ati China ni yoo kopa.