Lagos Chinese restaurant: Ayorinde ní Ìpínlẹ̀ Eko ń gbé ìgbésẹ̀ nípa ilé oúnjẹ elẹ́yàmẹ̀yà

Àkọlé fọ́nrán ohùn, Lagos Chinese restaurant: Ayorinde ní Ìpínlẹ̀ Eko ń gbé ìgbésẹ̀ nípa ilé oúnjẹ elẹ́yàmẹ̀yà

Komiṣọna fun eto igbafẹ ní Ipinlẹ Eko, Steve Ayorinde, ti ni ijọba kò tíì pari iwadii rẹ lori ile ounjẹ China kan ni ipinlẹ Eko to n gbe igbesẹ ẹlẹyàmẹya ti ko jẹ ki awọn ọmọ Naijiria ra ounjẹ.