Femi Okunronmu: Parliamentary pé wa ju ìsàjọba presidential lọ

Àkọlé fọ́nrán ohùn, Femi Okunronmu: Parliamentary pé wa ju ìsàjọba presidential lọ

Gbajugbaja oloselu, Femi Okunronmu ti kan saara si awọn asofin to buwọlu abadofin to fi agbara fun isejọba awọn asofin(parliamentary) lati rọpọ isejọba to fi agbara fun aarẹ.

Femi Okunronmu to sọ eyi lasiko to n ba BBC sọrọ ni awọn eniyan bi ti oun to n ja fun atunọ Naijiria naa ti n ja fun isejọba to fi agbara fun awọn asofin lorilẹede Naijiria.