Ìkọlù Plateau: Àwọn Krìstẹ́nì ṣe ìwọ́de ni ìlú Jos

Àwọn olùwọ́de ní kò dín ní igba èníyàn tó kú bó tilẹ̀ jẹ́ pé ènìyàn mẹ́rindinlaadọrin ni àwọn ọlọ́pàá ń tẹnumọ́.

Àwọn Krìstìanì ṣe ìwọ́de ni Jos
Àkọlé àwòrán, Àwọn Krìstìanì ṣe ìwọ́de ni Jos
Àwọn Krìstìanì ṣe ìwọ́de ni Jos
Àkọlé àwòrán, Pẹ̀lu aṣọ dudu, wọn ni o to gẹ́
Àwọn Krìstìanì ṣe ìwọ́de ni Jos
Àkọlé àwòrán, Àwọn Krìstìanì ṣe ìwọ́de ni Jos
Àwọn Krìstìanì ṣe ìwọ́de ni Jos
Àkọlé àwòrán, Ọ̀gọ̀rọ̀ àwọn Krìstìanì ló jáde fun iwọde naa
Àwọn Krìstìanì ṣe ìwọ́de ni Jos
Àkọlé àwòrán, Àwọn Krìstìanì ṣe ìwọ́de ni Jos
Àwọn Krìstìanì ṣe ìwọ́de ni Jos
Àkọlé àwòrán, Wón ni o to gẹ́
Àwọn Krìstìanì ṣe ìwọ́de ni Jos
Àkọlé àwòrán, Wọ́n f'orin arò s'ẹ́nu lati fẹ̀rúnú hàn
Àwọn Krìstìanì ṣe ìwọ́de ni Jos
Àkọlé àwòrán, Wọ́n ní, irọ́ o, àwọn to ku lé nigba