Ọ̀dún kẹẹ̀ta rèé tí Ààrẹ Buhari gorí oyè

Àkọlé fídíò, Àyájọ́ ọjọ́ ìjọba Tiwa n' tiwa, kí la ti se?

Fídíò yìí se àfihàn àwọn ìlérí ìjọba Ààrẹ Buhari nígbà tó gba èku idà àti ibi tí gbogbo ẹ̀ dé dúró.

Àwọn iròyin tì ẹ leè ní ìfẹ̀ síí: