You’re viewing a text-only version of this website that uses less data. View the main version of the website including all images and videos.
Ẹrijiyan Ekiti ni Omi Erin wa
Omi Erin to wa ni ilu Erijiyan Ekiti jẹ omi ti wọn kii pa ẹja rẹ, nitori ti wọn ba se, ko ni jina gẹgẹ bi ọmọ ilu naa ti sọ.