Awọn ẹya Fulani to ngbe pẹlu awọn Yoruba

Àkọlé fídíò, Arakunrin Fulani ni aigbede ara eni ni orisun ija pelu agbe

"Emi ti mo n sọrọ yi, ọmọ Yoruba ni iyawo mi. Amọ ara wa latipasẹ mọlẹbi, taa si fẹ ara wa. ko si ija abi aawọ laarin wa, nse la n gbe bii tmọ-tiya."