Ipele to nira:
Tẹ́ ibi lati ka itọni - Fi ọrọ Geesi we eda ọrọ rẹ ni Yoruba
- Lati safiwe, tẹ odo to wa lẹba ọrọ Geesi, ki o si tun tẹ odo to sunmọ eda rẹ ni ede Yoruba
- Tẹ bọtini to wa labẹ idanwo yi lati wo iye to gba
- Sun siwaju lati ipele ikarun si omiran
- Ipele marun lo wa.Ri daju wipe o pari gbogbo wọn!
Bawo lo se gbọ Yoruba si?
Oni ni ayajọ ede abinibi lagbaye, akori fun ọdun 2019 ni '''Ede abinibi se pataki fun idagbasoke, alaafia ati ipẹtu saawọ''
O rorun (awọn eranko)
- Bat - Adan
- Camel - Rakunmi
- Cow - Maalu
- Ostrich - Ogongo
- Lizard - Alangba
- Swan - Pẹpẹyẹ odo
- Tiger - Ẹkun
- Bat - Adan
Ko nira
- Five Hundred - Ẹẹdẹgbẹta
- Fifty - Aadọta
- Seven Million - Miliọnu meje
- Five Thousand - Ẹgbẹrun marun
- Twenty Five - Marundinlọgbọn
- Thirty Five - Marundinlogoji
- Seventy Five - Marundinlọgọrin
- Five Hundred - Ẹẹdẹgbẹta
O nira (omi)
- Ocean - Okun
- Lake - Adagun odo
- River - Odo
- Pond - Adagun odo kekere
- Stream - Odo to n san
- Dam - Adagun odo omi ẹrọ
- Spring - Odo kekere to n san
- Ocean - Okun





