A sẹ̀sẹ̀ fi èsì ìdìbò tuntun síta

Bó se ń lọ, làá ń tẹ̀le

Ìgbà táa kéde gbẹ̀yìn níbí: Thursday, September 27th 2018, 10:53 pm
  1. News image
    Gboyega Oyetola
    255505
    APC
  2. News image
    Sẹ́nétọ̀ Ademola Adeleke
    255023
    PDP
Wo èsì àtúndì ìbò gómìnà ní Ìpínlẹ̀ Osun bí ó ti ń jáde ní yàjóyàjó

Àkójọpọ̀ èsì ìbò

Ẹ tẹ bọ́tìnì ìjọba ìbílẹ̀ kọ̀ọ̀kan nísàlẹ̀ láti wá èsì jáde
WardADPAPCADCPDPSDP
Ife North10 PU2 0 126 0 2 0
Ife South7, 8 0 455 0 36 2
Orolu8, 9 1 280 0 122 1
Osogbo Ataoja5 PU017 0 299 0 165 1
ìdìbò tó kẹ́yìn- 49744 254345 7681 254698 128049
Àpapọ̀ èsì ìbò (Total): - 497452555057681255023128053

Kínni ó ṣe okùnfà àtúndì ìbò?

254,698
PDP
254,345
APC
353
Iye tí wọ́n fi jura wọn lọ
3,498
ibo tí wọ́n wọ́gi lé

Àjọ INEC kéde pé ìbò gómìnà Ìpínlẹ̀ Osun yóò di àtúndì lọ́jọ́ Aiku, ọjọ́ kẹtàlélógún oṣù kẹsan ọdún 2018

ìdí ni pé àlàfo tó wà láàrin àwọn olùdíje méjì tí wọ́n rí ìbò jù kéré sí iye àwọn tó f'orúkọ sílẹ̀ ní ibùdó ìdìbò tí wàhálà ti ṣẹlẹ̀

Ìbò 3,498 ni wọ́n wọ́gi lé ní ibùdó méje.