Ilé Arugbo Saraki: Ramoni padà wólé arúgbó ní Ilọrin!

Laago mẹrin idaji aarọ yii ni ijọba wa wo ile arugbo ti Bukola Saraki ni kí wọn ma wo tẹlẹ, ọrọ bẹ́yìn yọ.