You’re viewing a text-only version of this website that uses less data. View the main version of the website including all images and videos.
Sex Education: Ẹkọ ibálopọ̀ ko tó l'awọ́n ọ̀dọ́ ṣe ń wá a lorí ayélujára
Àwọn kùdìẹ̀-kudiẹ̀ tó wà lárá àwọn fíìmù ìbálòpọ( Porn) tó pọ̀ káàkiri lóri ẹrọ ayélujara ló mú ki Erika Lust dide láti yìí àpilẹkọ náà pada nípa obìnrin lásìkò ìbálòpọ̀.
O ní ìgbádun ọkùnrin lásan ni èyi wà fún nítori o máa ń se àfihàn bi ẹni pé ọkunrin níkan lo ni ẹtọ láti gbàdun ìbálopọ̀, Obinrin náà a máa gbádun rẹ̀ bákan náà bi àwọn ọkùnrin ṣe n gbádun rẹ.
Erika ni o yẹ ki àyipada bá irú àlàsílẹ̀ yìí, nítori pé ẹkọ kò oọ̀ to lórí ọ̀rọ̀ ìbálopọ̀, èyí sì ló fàá ti àwọn ọdọ́ ayé ode oni fí máa n tú orí ẹrọ ayelujara ká láti wadìí ìbálopọ àti láti wo àwọn fíìmù náà.
Sùgbọ́n gẹ́gẹ́ bi o ṣe sọ kí lo fàá ti àwọn lásẹ àtẹjisẹ Instgram yóò fi maa yọ ìpolowó irú awọ́n to ṣe ǹkan báyìí kúrò lórí àtagbà wọ́n, wọ́n jẹ́ ko nira fáwọn alátẹ̀lé oun láti ṣe àwọn ǹkan to wu wọ́n lorí Instagram
O ní fíìmù àgbéléwò títi òun ni láti mú àyípada bá àwọn ǹkan tí àwọn ènìyàn ti mọ tẹ́lẹ̀