Ọ̀gá àgbà ilé isẹ́ panápaná ní Eko ti pàrọwà sí àwọn ènìyàn láti má se mu sìgá nínú ilé.