You’re viewing a text-only version of this website that uses less data. View the main version of the website including all images and videos.
‘Ọmọ meji daku ninu eefi Olusosun’- Olugbe agbeegbe naa
Awọn to n gbe lagbeegbe naa ati awọn onisowo so ipa buburu ti eefi to ti n jo fun ọsẹ kan bayii, ti ko lagọ ara naa ati lori karakata lagbeegbe naa.