You’re viewing a text-only version of this website that uses less data. View the main version of the website including all images and videos.
Kini ‘technology’ ni ede Yoruba
Awọn ọmọ Yoruba fi ero wọn han lori ohun ti Yoruba npe 'technology'.
BBC Yoruba ko fẹ ki ede Yoruba parun la ṣe ṣagbekalẹ eto Bawo ni iwọ ṣe gbọ ede Yoruba tó yii?