You’re viewing a text-only version of this website that uses less data. View the main version of the website including all images and videos.
Kò ṣe é má gbọ̀ ọ́
Ile ifowopamọ agba Naijiria, CBN, tun gbe tuntun de ?
Ki ni wọn tun ṣe ?
CBN sọ pe ẹgbẹrun lọna ọgọrun-un naira ni gbedeke owo teeyan le gba lojumọ lori POS
Uhnnn?
Bakan naa ni awọn oni POS ko le san ju miliọnu kan ati igba naira lọ lojumọ
Ki wa ni wọn lo de ninu airowo gba yii?
Iyoku iroyin wa ni bbc.com/yoruba
................................................................................................................................................
Gomina ipinlẹ Osun, Ademola Adeleke ti paṣẹ itusilẹ Segun Olowookere, ọdmọkunrin ti wọn dajọ iku fun nitori poji adiyẹ
Ọdun 2010 ni awọn ọlọpaa mu Segun ati awn mii nigba to wa lọmọ ọdun mẹtadinlogun
...................................................................................................................................................
Ko din ni mọde kan to ku nibi apejẹ ipari ọdun ti olori Ooni tẹlẹ, Naomi Ogunwusi ṣe niluu Ibadan
Ikunle abiamọ o
Iroyin sọ pe akọlukọgba ṣẹlẹ, awọn eeyan tẹra wọn pa lai pẹ ti eto bẹrẹ ljọru
Nibo lo wa de duro bayii
Ẹkunrẹrẹ wa ni bbc.com/yoruba