Kò ṣe é má gbọ̀ ọ́

Kò ṣe é má gbọ̀ ọ́

Adura lo le ṣee, ọmọ Naijiria, ẹ gbdura fawọn olori yin

Aarẹ Bola Tinubu lo sọrọ yii bo ti n kawọn ọmọlẹyin Kristi ku ọdun Keresimesi lonii

Tinubu rọ awọn kristẹni lati fi ẹmi ifẹ ati iṣọkan han sawọn eeyan bi wọn sẹ yayọ ọdun Keresimesi

Aarẹ ni o doun loju wi pe ọjọ iwaju Naijiria yoo dara

''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''

Nibi talayọ ti n yọ lẹlẹkun ti n sunkun

Eledua o ni jẹ ka rọrọ ẹkun o

Amin o, amọ, ọpọ ẹbi lo ti wa ninu ibanujẹ bayii lẹyin ti baalu akero kan ja ti ọpọ ẹmi si ṣofo

Ha! Lọjọ ọdun keresimesi, nibo ni baalu ọhun ti ja

Kan soju BBC.Com/Yoruba ti o ba fẹ mọ

''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''

Ifa ni ẹ jẹ o mọba, ẹ ma tọwọ osẹlu bọọ

Idile ọba Bilaro Olu-Odo lo ṣe kilọ lori iroyin to ni

Ijọba ipinlẹ Osun ti yan ọmọ oye ti yoo jẹ Ọwa Obokun ilẹ Ijesa tuntun

Láìpẹ́ yìí ni ilé ẹjọ́ gíga ti ìpínlẹ̀ Osun dá Gómìnà Ademola Adeleke àtàwọn afọbajẹ lọ́wọ́ kọ́ láti yan Owa Obokun tuntun fún ilẹ̀ Ijesa.