You’re viewing a text-only version of this website that uses less data. View the main version of the website including all images and videos.
Kò ṣée mà gbọ̀ọ́
Ileeṣẹ Aarẹ Naijiria da a pada fun kootu America lori ẹsun oogun olooro ti ajọ FBI n wadii nipa Aarẹ Tinubu
Agbẹnusọ Aarẹ, Bayo Onanuga, sọ lọjọ Aiku pe ko si tuntun kan labẹ ọrun.
Onanuga ni FBI ko le ri ẹsun oogun oloro ka si Aarẹ lẹsẹ
Ka ẹkunrẹrẹ ni BBC.COM/YORUBA
,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,
Ajínigbé jí àádọ́ta èèyàn gbé ni Zamfara
Miliọnu lọna ọgọrun ni wọn n beere fun itusílẹ̀
ilu Banga ati Gidan Giji leyi ti waye.
Olugbe Banga kan sọ pe awọn agbebọn ti gba ilu mawọn lọwọ
O ni ojumọmọ ni wọn n gun ọkada wọlu pẹlu nnkan ija
;;;;;;;;;;;;;;;;;;;;;;;;;;;;;;;;;;;;;;;;;;;;;;;;;;;;;;;;;;;;;;;;;;;;;;;;;;;;;;
Portable tún dèrò kootu nitori Saheed Osupa
Ana ni ọlọpaa mu Habeeb Okikiola, Portable, l'Abeokuta, wọn si gbe e lọ si Kwara.
BBC Yoruba wa ni kootu loni ọjọ Aje ti wọn foju rẹ han lori ẹsun ibanilorukọjẹ, idunkookomọni atawọn mi-in ti Oṣupa fi kan an.
Aipẹ yii ni Were olorin sọrọ abuku s'Osupa nitori orin rẹ
Ile ọti kan tun ni Were olorin jẹ awọn ni miliọnu mẹfa naira
Owo ọti ni abi kinla
Fun ẹkunrẹrẹ