You’re viewing a text-only version of this website that uses less data. View the main version of the website including all images and videos.
Kò ṣe é má gbọ̀ ọ́
Onimọ nipa eto ọrọ aje kan ni Naijiria, Pat Utomi ni awọn ti gbe ijọba mii dide to pe ni shadow government
Lati maa ṣafihan awọn kudiẹkudiẹ to ba n waye ninu iṣejọba Tinubu
Amọ amofin agba Ahmed Raji ṣalaye fun BBC pe kii ṣe labẹ iru ijọba ti Naijiria n lo ni igbesẹ naa ti le waye
Gbọ na, ki lo n jẹ shadow government?
Ẹkunrẹrẹ alaye nipa rẹ wa loju opo bbc.com/yoruba
xxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxx
Ètò yíyan póòpù tuntun ti bẹ̀rẹ̀
Lẹyin tawọn cardinal kaakiri agbaye ti kalẹ si Roomu
Aago meje owurọ ọjọru ni eto yiyan poopu naa gberasọ ti yoo si wa sopin laago mẹfa irọlẹ
Ṣe pe a maa mọ ẹni yoo di poopu tuntun lonii?
O le ma ri bẹẹ o, kan soju opo bbc.com/yoruba lati mọ bi eto naa ṣe maa ri
xxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxx
O di gbere, o darinako, o tun di bẹni ba n jọni
Baalẹ Oluyole, Yemi Ogunyemi ti dagbere faye
Ọjọ Iṣẹgun ni agba ọjẹ nidi igbohunsafẹfẹ naa, to di ilumọọka latara eto E n ba laya jade laye lẹyin aisan
Fun ẹkunrẹrẹ