You’re viewing a text-only version of this website that uses less data. View the main version of the website including all images and videos.
Venezuela: Ọ̀pọ̀ ìdílé tí ebi ń pa, ti ń ta àwọn ọmọ wọn
Arabinrin kan ní ilẹ Venezuela to ta ọmọ rẹ nitori ọwọngogo ounjẹ ti ni, ohun ibanujẹ lo jẹ fun oun, bi oun ko se wa pẹlu ọmọ òun.
Obinrin naa ta ọmọ rẹ lẹyin to ti ni oyun osu mẹfa ninu.
Ọpọlọpọ ọmọ lo n sagbe, ti wọn si n sa ilẹ jẹ lati le fi tọ ara wọn nitori ọrọ aje wọn to dẹnu kọlẹ loriẹede Venezuela naa.