You’re viewing a text-only version of this website that uses less data. View the main version of the website including all images and videos.
So Láyà: Mr Latin, gbajúmọ̀ òṣèré tíátà kópa nínú ìdánwò nípa àṣà àti èdè Yorùbá
Mr Latin gbajúmọ̀ òṣèré tíátà kópa lórí ètò So Laya tí BBC Yorùbá ṣe fun un.
Nibẹ si ni o ti dahun awọn ibeere lọkan o jọkan eyi to nii se pẹlu ede Yoruba, asa ati ise wa.
Awada kẹrikẹri gbaa si ni awọn ọna ti agba osere naa gba dahun awọn ibeere naa, eyi to pa ni lẹrin pupọ.
Ẹ wa nnkan fidi le, lati gbadun awọn idahun Mr Latin lori ibeere ti BBC Yoruba bi lori eto wa, So Laya.