You’re viewing a text-only version of this website that uses less data. View the main version of the website including all images and videos.
Kids building mosques in Ilorin: Láti kékeré la ti ń kọ́ Mọ́sálásí ilé alamọ̀ bíi àwọn bàbá wa - Abdulmumeen Abdubakare
"Toru toru la maa n ṣiṣẹ lati jẹ ki Mọsalasi yii di kikọ pari. Inu wa maa n dun pe bi awọn agba ba ti n pe irun ni Mọsalasi nla tọdọ wọn lọhun, awa naa a maa se tiwa niwọnba tiwa nibi".
Awọn ọmọde yii ba BBC Yoruba sọrọ lori iṣẹ laada ti wọn n ṣe paapaa bo ṣe bọ si asiko Ramadan tii ṣe oṣu awẹ awọn Mususlumi.