You’re viewing a text-only version of this website that uses less data. View the main version of the website including all images and videos.
Rape cases in Nigeria: Ọmọ ọdun 5 àti 14 ni Kalu wà nígbà tí obìnrin fipá ba lòpọ̀
Ni orilẹede Naijiria ati lawujọ agbaye patapata, isẹlẹ ifipabanilopọ ti di tọrọ fọn kale.
Awọn obinrin si ni isẹlẹ naa maa n kan julọ, ti kii si saba wọpọ pe ki obinrin fipa ba ọkunrin lopọ.
Sugbọn nigba to n ba BBC sọrọ, ọkunrin kan ta fi orukọ ati ohun bo ni aṣiri, amọ ta sọ ni Kalu salaye pe ẹẹmeji ọtọọtọ lawọn obinrin ti fi tipa ba ohun lopọ.
Àwọn iròyin tì ẹ leè ní ìfẹ̀ síí:
- Ìdí rèé tí mi ò fi yọjú sí ìgbìmọ̀ àjọ PFN- Fatoyinbo
- Ọ̀rọ̀ ìfipábánilòpọ̀ di kàyééfì lásìkò yìí; ọwọ́ tẹ àwọn kan ní Ekiti
- Obìnrin kan rèé tó sọ ìrírí rẹ̀ lẹ́yìn tí ọkùnrin mẹ́ta fipá báa lòpọ̀
- Iyabo Ojo, Toyin Abraham, Mercy Aigbe, ta làwọn òṣèrébìnrin yìí gbè lẹ́yìn lórí ọ̀rọ̀ ìfipábánilòpọ̀?
- Ìfipábánilòpọ̀ kìí ṣe ìwà ọmọlúwàbí, àwọn òṣèré tíátà pariwo síta
- Ìdájọ́ ikú ni a fẹ́ fún àwọn afipábánilòpọ̀ - Ẹgbẹ́ ajàfẹ́tọmọnìyàn
Kalu ni nigba ti oun wa ni ọmọ ọdun marun ati mẹrinla ni isẹlẹ naa waye.
O wa fikun pe, awọn isẹlẹ ifipabanilopọ mejeeji tawọn obinrin to sun mọ oun pupọ se si oun yii, ko jẹ ki oun nigbagbọ mọ ninu ẹnikẹni.
- Ẹfunroye Tinubu - Ògbóǹtagí oníṣòwò, olówò ẹrú àti afọbajẹ
- Samuel Ajayi Crowther, òjíṣẹ́ Ọlọ́run tó gbé èdè Yoruba lárugẹ
- Mọrèmi Àjàṣorò, akọni obìnrin tó gba Ilé Ifẹ̀ sílẹ̀ lóko ẹrú
- Ọ̀rọ̀ǹpọ̀tọ̀niyùn, Aláàfin obìnrin àkọ́kọ́ rèé, tó ní nǹkan ọkùnrin
- Ṣé ìwọ mọ odò adágún Adó Àwáyè tí kò ní òpin ní ìsàlẹ̀?
Alaye ree lori bi awọn isẹlẹ ifipabanilopọ naa se waye, ẹ wo o.