You’re viewing a text-only version of this website that uses less data. View the main version of the website including all images and videos.
Wo àwọn nǹkan mẹ́rin tó yẹ kó wà nínú báàgì rẹ lásìkò Covid-19 yìí
Ajọ to n ri si eto ilera lagbaye, WHO ti sọ pe imọtoto araẹni lee dabo bo eeyan lasiko ajakalẹ arun Covid-19 yi.
Yatọ si fifọ ọwọ pẹlu ọṣẹ, lilo ibomu atawọn nkan mii to yẹ ni ṣiṣe, ki ni awọn nnkan mii ti eeyan tun le ṣẹ lati dabo ara tabi ohun ini rẹ lasiko yi?
BBC Yoruba yannana gbogbo bo ṣe jẹ ninu fidio to wa loke yi.
- Aláboyún ọmọ Naijiria bímọ nínú bàálù tó ń gbé wọn bọ̀ láti Dubai
- Auxiliary ń ní wá lára pẹ̀lú gbígba owó aitọ, a ń ko ọkọ̀ wa kúrò lójú pópó - Awakọ èrò
- Ayẹwò kò dáwọ́ dúro botílẹ̀ jẹ́ pé èròjà ayẹwò (Reagents) kò si mọ́
- Ayinla Ọmọwura, orin èébú àti oríyìn lo fi di ọ̀rẹ́ àwọ̀n obìnrin
- Mẹ́rin nínú àwọn mọ́kànlá tó ń bọ̀ láti Sokoto tí wón mú l'Oyo ló ní Coronavirus
- Kí ló wà nínú àbá àkóso ajakalẹ àrùn tó fi ní àtakò?