You’re viewing a text-only version of this website that uses less data. View the main version of the website including all images and videos.
Cancer Survivor: Àìsàn jẹjẹrẹ ọyàn ṣe wò, ta bá tètè ṣe àkíyèsí rẹ̀, ká sì lọ sílé ìwòsàn
Lẹnu lọọlọ yii, ọpọ obinrin lo n koju aisan jẹjẹrẹ ọyan, ti wọn si n baa lọ.
Amọ obinrin kan ree ti ori ko yọ lọwọ aisan asekupani naa, Arabinrin Bolanle Uwaje salaye ọna to gba to fi bọ lọwọ aisan naa.
Bakan naa lo sọ ohun to yẹ ki awọn obinrin maa se lati bọ lọwọ itiju aisan jẹjẹrẹ ọyan.