Ilé ẹjọ́ gíga kún fọfọ lori igbẹ́jọ́ Omoyele Sowore l'Abuja

Awọn agbẹjọro ti wa ni ikalẹ ti wọn si n reti adajọ ati Sowore ti wọn fẹsun kan lati yọju si ile ẹjọ giga l'Abuja