You’re viewing a text-only version of this website that uses less data. View the main version of the website including all images and videos.
Lafup: Kò sí ẹni kankan tó ń ṣe ẹ̀fẹ̀ ní Ibadan nígbà táwa bẹ̀rẹ̀
Adẹrinpoṣonu ti ko ṣee fọwọ rọ sẹyin ni Oluwasegun Ogundipe ti gbogbo eniyan mọ si Lafup jẹ ni ilu Ibadan.
O fọwọ rẹ sọya pe ko si ẹni kankan ti o n ṣe ẹfẹ niluu Ibadan nigba ti oun fi bẹrẹ titi ti ohun fi wa di ẹni ti wọn mọ kaakiri Naijiria bayii.
Nigba ti owo ṣi ni iyi lo ti bẹrẹ to jẹ wi pe ati san aadọta naira pere gun awọn eniyan lara ṣugbọn o jẹ ki awọn eeyan mọ iyi owo ti wọn n san nigba naa lati wa fi wo awọn ẹfẹ rẹ.